Súrà 60 · Júzù 28
Al-Mumtahanah · 60:6
لَقَدْ كَانَ لَكُمْ فِيهِمْ أُسْوَةٌ حَسَنَةٌ لِمَنْ كَانَ يَرْجُو اللَّهَ وَالْيَوْمَ الْآخِرَ ۚ وَمَنْ يَتَوَلَّ فَإِنَّ اللَّهَ هُوَ الْغَنِيُّ الْحَمِيدُ
Dájúdájú àwòkọ́ṣe rere ti wà fun yín ní ara wọn fún ẹni t’ó ń retí (ẹ̀sán) Allāhu àti Ọjọ́ Ìkẹ́yìn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá pẹ̀yìn dà, dájúdájú Allāhu, Òun ni Ọlọ́rọ̀, Ẹlẹ́yìn.
Tafsír
Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.
6. This good example is only followed by those who have hope for good from Allah in the world and afterlife. Those who turn away from this good example, then Allah is in no need of His servants. He does not require their obedience and He is worthy of praise in every state.
Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún