Súrà 60 · Júzù 28
Al-Mumtahanah · 60:5
رَبَّنَا لَا تَجْعَلْنَا فِتْنَةً لِلَّذِينَ كَفَرُوا وَاغْفِرْ لَنَا رَبَّنَا ۖ إِنَّكَ أَنْتَ الْعَزِيزُ الْحَكِيمُ
Olúwa wa, má ṣe wá ní àdánwò fún àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́. Foríjìn wá, Olúwa wa. Dájúdájú Ìwọ ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n."
____________________
Ìyẹn ni pé, má fi àwọn kèfèrí borí wa, kí ayé má fi lérò pé wọ́n wà lórí òdodo ni wọ́n fi borí wa.
____________________
Ìyẹn ni pé, má fi àwọn kèfèrí borí wa, kí ayé má fi lérò pé wọ́n wà lórí òdodo ni wọ́n fi borí wa.
Tafsír
Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.
5. O our Lord! Do not make us a trial for the disbelievers by giving them power over us, so they can say: “If they were on the truth we would not have been given power over them”, and O our Lord forgive our sins for us, because indeed, You are the Almighty who can never be overpowered; the Wise in your creation, legislation and decree.
Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún