Al-Muyassar

Ibrahim · 14:49

وَتَرَى الْمُجْرِمِينَ يَوْمَئِذٍ مُقَرَّنِينَ فِي الْأَصْفَادِ

O sì máa rí àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ní ọjọ́ yẹn, tí wọn yóò so wọ́n papọ̀ mọ́ra wọn sínú sẹ́kẹ́sẹkẹ̀.

Tafsír yìí wà ní èdè Lárúbáwá. Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Ka Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì: Al-Mukhtasar (English)

وتُبْصِرُ -أيها الرسول- المجرمين يوم القيامة مقيدين بالقيود، قد قُرِنت أيديهم وأرجلهم بالسلاسل، وهم في ذُلٍّ وهوان.

14:49 · Al-Muyassar

Al-Muyassar - Ibrahim 14:49 · Tlawati