Al-Qadr

سورة القدر

Súrà 97 · Mákí · 5 àwọn ẹsẹ

97:1 · Laylat al-QadrJúzù 30 · ojú. 598

إِنَّا أَنْزَلْنَاهُ فِي لَيْلَةِ الْقَدْرِ1

Dájúdájú Àwa sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ nínú Òru Abiyì.
____________________
Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ fún sūrah al-’Isrọ̄’; 17:106.
97:2Júzù 30 · ojú. 598

وَمَا أَدْرَاكَ مَا لَيْلَةُ الْقَدْرِ2

Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun t’ó ń jẹ́ Òru Abiyì?
97:3Júzù 30 · ojú. 598

لَيْلَةُ الْقَدْرِ خَيْرٌ مِنْ أَلْفِ شَهْرٍ3

Òru Abiyì lóore ju ẹgbẹ̀rún oṣù lọ.
97:4Júzù 30 · ojú. 598

تَنَزَّلُ الْمَلَائِكَةُ وَالرُّوحُ فِيهَا بِإِذْنِ رَبِّهِمْ مِنْ كُلِّ أَمْرٍ4

Àwọn mọlāika àti Jibrīl yó sì máa sọ̀kalẹ̀ nínú òru náà pẹ̀lú àṣẹ Olúwa wọn fún gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan.
97:5Júzù 30 · ojú. 598

سَلَامٌ هِيَ حَتَّىٰ مَطْلَعِ الْفَجْرِ5

Àlàáfíà ni òru náà títí di àsìkò àfẹ̀mọ́júmọ́.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà