Súrà 60 · Júzù 28
Al-Mumtahanah · 60:9
إِنَّمَا يَنْهَاكُمُ اللَّهُ عَنِ الَّذِينَ قَاتَلُوكُمْ فِي الدِّينِ وَأَخْرَجُوكُمْ مِنْ دِيَارِكُمْ وَظَاهَرُوا عَلَىٰ إِخْرَاجِكُمْ أَنْ تَوَلَّوْهُمْ ۚ وَمَنْ يَتَوَلَّهُمْ فَأُولَٰئِكَ هُمُ الظَّالِمُونَ
Ohun tí Allāhu kọ̀ fun yín nípa àwọn t’ó gbógun tì yín nínú ẹ̀sìn, tí wọ́n sì lè yín jáde kúrò nínú ìlú yín, tí wọ́n tún ṣe ìrànlọ́wọ́ (fún àwọn ọ̀tá yín) láti le yín jáde, ni pé (Ó kọ̀ fun yín) láti mú wọn ní ọ̀rẹ́. Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú wọn ní ọ̀rẹ́, àwọn wọ̀nyẹn, àwọn ni alábòsí.
Tafsír
Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.
9. Allah only prohibits you from those who fought you on account of your faith, expelled you from your homes and aided in your expulsion. He prohibits you from aligning yourselves with them. Those of you who align themselves with them, they are the ones who wrong themselves by bringing them to the point of destruction on account of their going against Allah’s instruction.
Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún