Súrà 59 · Júzù 28

Al-Hashr · 59:2

هُوَ الَّذِي أَخْرَجَ الَّذِينَ كَفَرُوا مِنْ أَهْلِ الْكِتَابِ مِنْ دِيَارِهِمْ لِأَوَّلِ الْحَشْرِ ۚ مَا ظَنَنْتُمْ أَنْ يَخْرُجُوا ۖ وَظَنُّوا أَنَّهُمْ مَانِعَتُهُمْ حُصُونُهُمْ مِنَ اللَّهِ فَأَتَاهُمُ اللَّهُ مِنْ حَيْثُ لَمْ يَحْتَسِبُوا ۖ وَقَذَفَ فِي قُلُوبِهِمُ الرُّعْبَ ۚ يُخْرِبُونَ بُيُوتَهُمْ بِأَيْدِيهِمْ وَأَيْدِي الْمُؤْمِنِينَ فَاعْتَبِرُوا يَا أُولِي الْأَبْصَارِ

Òun ni Ẹni tí Ó mú àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ nínú àwọn ahlu-l-kitāb jáde kúrò nínú ilé wọn fún ìkójọ àkọ́kọ́. Ẹ̀yin kò lérò pé wọn yóò jáde. Àwọn náà sì lérò pé dájúdájú àwọn odi ilé wọn yóò dáàbò bo àwọn lọ́dọ̀ Allāhu. Ṣùgbọ́n Allāhu wá bá wọn ní ibi tí wọn kò lérò; Allāhu sì ju ìbẹ̀rù sínú ọkàn wọn. Wọ́n ń fi ọwọ́ ara wọn àti ọwọ́ àwọn onígbàgbọ́ òdodo wó àwọn ilé wọn. Nítorí náà, ẹ wòye, ẹ̀yin tí ẹ ní ojú ìríran.

Tafsír

Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

2. He is the one who exiled the Banū an-Naḍīr who had disbelieved in Allah and rejected His Messenger Muhammad (peace be upon him), from their houses in Al-Madīnah the first time towards the Levant region. They were from the Jews: the people of the Torah. After they had broken their treaty and sided with the idolaters against the Messenger, He exiled them towards the Levant. O believers! You did not think they would leave their homes because of the might and strength they possessed, and they themselves thought that their fortresses they had fortified would protect them from the might of Allah and His punishment. Then, the might of Allah came upon them in a manner they did not anticipate, when He commanded His Messenger to fight them and exile them from their homes. Allah also put extreme fear into their hearts, and they began demolishing their homes with their own hands from the inside so that the believers could not take advantage of them, while the Muslims demolished them from the outside. O people of insight! So take heed of what befell them due to their disbelief and do not be like them, in case you get the same requital as they did, and face the same punishment they faced.

Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún