Súrà 49 · Júzù 26

Al-Hujurat · 49:4

إِنَّ الَّذِينَ يُنَادُونَكَ مِنْ وَرَاءِ الْحُجُرَاتِ أَكْثَرُهُمْ لَا يَعْقِلُونَ

Dájúdájú àwọn t’ó ń pè ọ́ láti ẹ̀yìn àwọn yàrá, ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ wọn ni kò ṣe làákàyè.

Tafsír

Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

4. O Messenger! Indeed, those bedouins who call out to you from behind the dwellings of your wives, the majority of them do not understand, so do not worry about them, because if they were understanding, they would surely show good manners to you and would definitely wait until you came out to them. Then, when you came out to them, they would speak to you about their matters by lowering their voices. However, most of them have not yet understood this.

Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún

Al-Hujurat 49:4 · Tlawati