Súrà 48 · Júzù 26
Al-Fath · 48:26
إِذْ جَعَلَ الَّذِينَ كَفَرُوا فِي قُلُوبِهِمُ الْحَمِيَّةَ حَمِيَّةَ الْجَاهِلِيَّةِ فَأَنْزَلَ اللَّهُ سَكِينَتَهُ عَلَىٰ رَسُولِهِ وَعَلَى الْمُؤْمِنِينَ وَأَلْزَمَهُمْ كَلِمَةَ التَّقْوَىٰ وَكَانُوا أَحَقَّ بِهَا وَأَهْلَهَا ۚ وَكَانَ اللَّهُ بِكُلِّ شَيْءٍ عَلِيمًا
(Rántí) nígbà tí àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ kó ìgbónára sínú ọkàn wọn ní ìgbónára ti ìgbà àìmọ̀kan, Allāhu sì sọ ìfọ̀kànbalẹ̀ kalẹ̀ fún Òjíṣẹ́ Rẹ̀ àti àwọn onígbàgbọ́ òdodo. Ó sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rù (Rẹ̀) wà pẹ̀lú wọn; Wọ́n ní ẹ̀tọ́ sí i jùlọ, àwọn ni wọ́n sì ni ín. Allāhu sì ni Onímọ̀ nípa gbogbo n̄ǹkan.
Tafsír
Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.
26. Remember when those who disbelieved in Allah and His Messenger harboured in their hearts the pride of ignorance; an ignorance that was linked to desires and not the truth. They haughtily rejected the entrance of the Messenger of Allah (peace be upon him) into Makkah the year of the treaty of Ḥudaybīyyah, fearing and blaming him that he would overpower them and take control over it. Therefore, Allah sent down tranquility from Himself upon the His Messenger and upon the believers so their anger did not lead to them confronting the idolaters with the same actions. Allah made the believers firm upon the statement of truth, i.e. ‘There is none worthy of worship except for Allah’, and kept them firm upon fulfilling its rights which they fulfilled. The believers were more worthy of this statement than others, and more deserving of it because of the goodness within their hearts that Allah knew of. And Allah is aware of everything; nothing is hidden from Him.
Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún