Súrà 2 · Júzù 2

Al-Baqarah · 2:143

وَكَذَٰلِكَ جَعَلْنَاكُمْ أُمَّةً وَسَطًا لِتَكُونُوا شُهَدَاءَ عَلَى النَّاسِ وَيَكُونَ الرَّسُولُ عَلَيْكُمْ شَهِيدًا ۗ وَمَا جَعَلْنَا الْقِبْلَةَ الَّتِي كُنْتَ عَلَيْهَا إِلَّا لِنَعْلَمَ مَنْ يَتَّبِعُ الرَّسُولَ مِمَّنْ يَنْقَلِبُ عَلَىٰ عَقِبَيْهِ ۚ وَإِنْ كَانَتْ لَكَبِيرَةً إِلَّا عَلَى الَّذِينَ هَدَى اللَّهُ ۗ وَمَا كَانَ اللَّهُ لِيُضِيعَ إِيمَانَكُمْ ۚ إِنَّ اللَّهَ بِالنَّاسِ لَرَءُوفٌ رَحِيمٌ

Báyẹn ni A ti ṣe yín ní ẹ̀ṣà ìjọ t’ó lóore jùlọ, nítorí kí ẹ lè jẹ́ ẹlẹ́rìí fún àwọn ènìyàn, àti nítorí kí Òjíṣẹ́ náà lè jẹ́ ẹlẹ́rìí fun yín. A kò sì ṣe Ƙiblah tí o wà lórí rẹ̀ tẹ́lẹ̀ ní ibùkọjú-kírun bí kò ṣe pé nítorí kí Á lè ṣe àfihàn ẹni tí ó máa tẹ̀lé Òjíṣẹ́ yàtọ̀ sí ẹni tí ó máa yísẹ̀ padà. Dájúdájú ó lágbára àyàfi fún àwọn tí Allāhu tọ́ sọ́nà. Allāhu kò sì níí fi ìgbàgbọ́ yín ráre. Dájúdájú Allāhu ni Aláàánú, Oníkẹ̀ẹ́ fún àwọn ènìyàn.

Tafsír

Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

143. Just as I made a direction of prayer for you, I have chosen you to be a good, just and balanced nation from among all the communities: in your beliefs and your ways of worship and in your transactions, so that you will be witnesses for the prophets of Allah on the Day of Judgement, confirming that they delivered the messages Allah instructed them to deliver to their people; and so that the Prophet Muhammad (peace be upon him) will also witness that he delivered his message to you. Allah changed the direction of prayer that you used to face (Jerusalem) to demonstrate who was content with Allah’s decree, willingly doing as He instructed and following the Messenger; and to also demonstrate who turned away from his religion, following his own desires and not obeying Allah’s sacred law. The first change of prayer direction was difficult, except for those who Allah granted faith to and who were certain that whatever He decrees for His servants has far reaching wisdom and underlying reasons behind it. Allah will not make you lose your faith in Him, or your good actions, including the prayers you prayed before the change of prayer direction. Allah is kind and compassionate with people, not overburdening them, and they will not lose the reward for their actions.

Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún

Al-Baqarah 2:143 · Tlawati