Súrà 16 · Júzù 14

Allah commands justice · An-Nahl 16:90

۞ إِنَّ اللَّهَ يَأْمُرُ بِالْعَدْلِ وَالْإِحْسَانِ وَإِيتَاءِ ذِي الْقُرْبَىٰ وَيَنْهَىٰ عَنِ الْفَحْشَاءِ وَالْمُنْكَرِ وَالْبَغْيِ ۚ يَعِظُكُمْ لَعَلَّكُمْ تَذَكَّرُونَ

Dájúdájú Allāhu ń pàṣẹ ṣíṣe déédé, ṣíṣe rere àti fífún ẹbí (ní n̄ǹkan). Ó sì ń kọ ìwà ìbàjẹ́, ohun burúkú àti rúkèrúdò. Ó ń ṣe wáàsí fun yín nítorí kí ẹ lè lo ìrántí.

Tafsír

Kò sí tafsír ní èdè rẹ. Èyí ni Al-Mukhtasar ní èdè Gẹ̀ẹ́sì.

90. Allah instructs His servants to be just, by discharging Allah’s rights and the rights of fellow human beings and by not giving preference in judgement to anyone unless with a right that demands such preference. He instructs them to be good, by doing more than what is mandatory such as spending voluntarily and forgiving the oppressor. He instructs them to see to the needs of their relatives. He forbids everything that is vile, in words, such as obscene speech, or in deeds, such as fornication. He forbids oppression and arrogance over people. Allah advises you with the instructions and prohibitions in this verse in the hope that you will take heed of His advice.

Ṣí nínú olùkà - Ka surah náà ní kíkún