Al-Kafirun

سورة الكافرون

Súrà 109 · Mákí · 6 àwọn ẹsẹ

109:1 · Al-KafirunJúzù 30 · ojú. 603

قُلْ يَا أَيُّهَا الْكَافِرُونَ1

Sọ pé: "Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́,
109:2Júzù 30 · ojú. 603

لَا أَعْبُدُ مَا تَعْبُدُونَ2

Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún.
109:3Júzù 30 · ojú. 603

وَلَا أَنْتُمْ عَابِدُونَ مَا أَعْبُدُ3

Ẹ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.
109:4Júzù 30 · ojú. 603

وَلَا أَنَا عَابِدٌ مَا عَبَدْتُمْ4

Èmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́.
109:5Júzù 30 · ojú. 603

وَلَا أَنْتُمْ عَابِدُونَ مَا أَعْبُدُ5

Ẹ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.
109:6Júzù 30 · ojú. 603

لَكُمْ دِينُكُمْ وَلِيَ دِينِ6

Tiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi."

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà