Quraysh

سورة قريش

Súrà 106 · Mákí · 4 àwọn ẹsẹ

106:1Júzù 30 · ojú. 602

لِإِيلَافِ قُرَيْشٍ1

(Ìkẹ́ ni láti ọ̀dọ̀ Allāhu) fún ìdílé Ƙuraeṣ láti wà papọ̀ nínú ààbò.
106:2Júzù 30 · ojú. 602

إِيلَافِهِمْ رِحْلَةَ الشِّتَاءِ وَالصَّيْفِ2

(Ìkẹ́ ni sẹ́ láti ọ̀dọ̀ Allāhu) fún wọn láti wà papọ̀ nínú ààbò lórí ìrìn-àjò ní ìgbà òtútù àti ìgbà ooru.
106:3Júzù 30 · ojú. 602

فَلْيَعْبُدُوا رَبَّ هَٰذَا الْبَيْتِ3

Nítorí náà, kí wọ́n jọ́sìn fún Olúwa Ilé (Ka‘bah) yìí.
106:4Júzù 30 · ojú. 602

الَّذِي أَطْعَمَهُمْ مِنْ جُوعٍ وَآمَنَهُمْ مِنْ خَوْفٍ4

Ẹni tí Ó fún wọn ní jíjẹ (ní àsìkò) ebi. Ó sì fi wọ́n lọ́kàn balẹ̀ nínú ìpáyà.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà