At-Takathur

سورة التكاثر

Súrà 102 · Màdíínà · 8 àwọn ẹsẹ

102:1Júzù 30 · ojú. 600

أَلْهَاكُمُ التَّكَاثُرُ1

Wíwá oore ayé ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ fún ìyanràn ṣíṣe ti kó àìrójú fẹ́sìn ba yín
102:2Júzù 30 · ojú. 600

حَتَّىٰ زُرْتُمُ الْمَقَابِرَ2

títí ẹ fi wọ inú sàréè.
102:3Júzù 30 · ojú. 600

كَلَّا سَوْفَ تَعْلَمُونَ3

Rárá (kò yẹ kó rí bẹ́ẹ̀, àmọ́) láìpẹ́ ẹ máa mọ̀.
102:4Júzù 30 · ojú. 600

ثُمَّ كَلَّا سَوْفَ تَعْلَمُونَ4

Lẹ́yìn náà, ní òdodo láìpẹ́ ẹ máa mọ̀.
102:5Júzù 30 · ojú. 600

كَلَّا لَوْ تَعْلَمُونَ عِلْمَ الْيَقِينِ5

Bẹ́ẹ̀ ni, tí ó bá jẹ́ pé ẹ ni ìmọ̀ àmọ̀dájú ni (ẹ̀yin ìbá tí ṣe bẹ́ẹ̀).
102:6Júzù 30 · ojú. 600

لَتَرَوُنَّ الْجَحِيمَ6

Dájúdájú ẹ máa rí iná Jẹhīm.
102:7Júzù 30 · ojú. 600

ثُمَّ لَتَرَوُنَّهَا عَيْنَ الْيَقِينِ7

Lẹ́yìn náà, dájúdájú ẹ máa rí i ní àrídájú.
102:8Júzù 30 · ojú. 600

ثُمَّ لَتُسْأَلُنَّ يَوْمَئِذٍ عَنِ النَّعِيمِ8

Lẹ́yìn náà, dájúdájú ní ọjọ́ yẹn wọ́n máa bi yín léèrè nípa ìgbádùn (ayé yìí).

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà