Al-Falaq

سورة الفلق

Súrà 113 · Mákí · 5 àwọn ẹsẹ

113:1 · Al-FalaqJúzù 30 · ojú. 604

قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ الْفَلَقِ1

Sọ pé: "Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù
113:2Júzù 30 · ojú. 604

مِنْ شَرِّ مَا خَلَقَ2

níbi aburú ohun tí Ó dá,
113:3Júzù 30 · ojú. 604

وَمِنْ شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ3

àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn,
113:4Júzù 30 · ojú. 604

وَمِنْ شَرِّ النَّفَّاثَاتِ فِي الْعُقَدِ4

àti níbi aburú àwọn (òpìdán) t’ó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè,
113:5Júzù 30 · ojú. 604

وَمِنْ شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ5

àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara."

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà