An-Nasr

سورة النصر

Súrà 110 · Màdíínà · 3 àwọn ẹsẹ

110:1 · An-NasrJúzù 30 · ojú. 603

إِذَا جَاءَ نَصْرُ اللَّهِ وَالْفَتْحُ1

Nígbà tí àrànṣe Allāhu (lórí ọ̀tá ẹ̀sìn) àti ṣíṣí ìlú (Mọ́kkah) bá ṣẹlẹ̀,
110:2Júzù 30 · ojú. 603

وَرَأَيْتَ النَّاسَ يَدْخُلُونَ فِي دِينِ اللَّهِ أَفْوَاجًا2

tí o sì rí àwọn ènìyàn tí wọ́n wọnú ẹ̀sìn Allāhu níjọníjọ,
110:3Júzù 30 · ojú. 603

فَسَبِّحْ بِحَمْدِ رَبِّكَ وَاسْتَغْفِرْهُ ۚ إِنَّهُ كَانَ تَوَّابًا3

nítorí náà, ṣàfọ̀mọ́ pẹ̀lú ìdúpẹ́ fún Olúwa rẹ. Kí o sì tọrọ àforíjìn lọ́dọ̀ Rẹ̀. Dájúdájú Ó ń jẹ́ Olùgba-ìronúpìwàdà.
____________________
Ẹ wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ fún sūrah Gọ̄fir; 40:55.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà

Fares Abbad - An-Nasr · Tlawati