An-Nas

سورة الناس

Súrà 114 · Mákí · 6 àwọn ẹsẹ

114:1 · An-NasJúzù 30 · ojú. 604

قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ النَّاسِ1

Sọ pé: "Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,
114:2Júzù 30 · ojú. 604

مَلِكِ النَّاسِ2

Ọba àwọn ènìyàn,
114:3Júzù 30 · ojú. 604

إِلَٰهِ النَّاسِ3

Ọlọ́hun àwọn ènìyàn,
114:4Júzù 30 · ojú. 604

مِنْ شَرِّ الْوَسْوَاسِ الْخَنَّاسِ4

níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni t’ó bá dárúkọ Allāh).
114:5Júzù 30 · ojú. 604

الَّذِي يُوَسْوِسُ فِي صُدُورِ النَّاسِ5

(Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.
114:6Júzù 30 · ojú. 604

مِنَ الْجِنَّةِ وَالنَّاسِ6

(Èṣù náà) wà nínú àlùjànnú àti ènìyàn.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà

Ali Jaber - An-Nas · Tlawati