Al-Kawthar

سورة الكوثر

Súrà 108 · Mákí · 3 àwọn ẹsẹ

108:1 · Al-KawtharJúzù 30 · ojú. 602

إِنَّا أَعْطَيْنَاكَ الْكَوْثَرَ1

Dájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.
108:2Júzù 30 · ojú. 602

فَصَلِّ لِرَبِّكَ وَانْحَرْ2

Nítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).
108:3Júzù 30 · ojú. 602

إِنَّ شَانِئَكَ هُوَ الْأَبْتَرُ3

Dájúdájú, ẹni t’ó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà