Al-Asr

سورة العصر

Súrà 103 · Mákí · 3 àwọn ẹsẹ

103:1 · Al-AsrJúzù 30 · ojú. 601

وَالْعَصْرِ1

Allāhu búra pẹ̀lú àkókò ìrọ̀lẹ́ ayé.
103:2Júzù 30 · ojú. 601

إِنَّ الْإِنْسَانَ لَفِي خُسْرٍ2

Dájúdájú ènìyàn wà nínú òfò.
103:3Júzù 30 · ojú. 601

إِلَّا الَّذِينَ آمَنُوا وَعَمِلُوا الصَّالِحَاتِ وَتَوَاصَوْا بِالْحَقِّ وَتَوَاصَوْا بِالصَّبْرِ3

Àyàfi àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ òdodo láààrin ara wọn, tí wọ́n sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ sùúrù láààrin ara wọn.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà

Ali Jaber - Al-Asr · Tlawati