Al-Fil

سورة الفيل

Súrà 105 · Mákí · 5 àwọn ẹsẹ

105:1Júzù 30 · ojú. 601

أَلَمْ تَرَ كَيْفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصْحَابِ الْفِيلِ1

Ṣé o ò rí bí Olúwa rẹ ti ṣe ọ̀rọ̀ ìjọ elérin ni?
105:2Júzù 30 · ojú. 601

أَلَمْ يَجْعَلْ كَيْدَهُمْ فِي تَضْلِيلٍ2

Ṣé kò sọ ète wọn di òfo bí?
105:3Júzù 30 · ojú. 601

وَأَرْسَلَ عَلَيْهِمْ طَيْرًا أَبَابِيلَ3

Ó sì rán àwọn ẹyẹ níkọ̀níkọ̀ sí wọn.
105:4Júzù 30 · ojú. 601

تَرْمِيهِمْ بِحِجَارَةٍ مِنْ سِجِّيلٍ4

Wọ́n ń jù wọ́n ní òkúta amọ̀ (t’ó ti gbaná sára).
105:5Júzù 30 · ojú. 601

فَجَعَلَهُمْ كَعَصْفٍ مَأْكُولٍ5

Ó sì sọ wọ́n di bíi èrúnrún koríko àjẹkù gbígbẹ.

Ṣeré láti ìbẹ̀rẹ̀ súrà