Yoruba

An-Nisa · 4:118

لَعَنَهُ اللَّهُ ۘ وَقَالَ لَأَتَّخِذَنَّ مِنْ عِبَادِكَ نَصِيبًا مَفْرُوضًا

Перевод

Allāhu ṣẹ́bi lé Èṣù. Ó sì wí pé: "Dájúdájú mo máa mú ìpín tí wọ́n pín fún mi nínú àwọn ẹrúsìn Rẹ.

Тафсир на вашем языке

Тафсиры на арабском

Перевод

Слушать

Yoruba - An-Nisa 4:118 · Tlawati