Yoruba

Nuh · 71:14

وَقَدْ خَلَقَكُمْ أَطْوَارًا

ߘߟߊߡߌߘߊ

Ó sì kúkú ṣẹ̀dá yín láti ìrísí kan sí òmíràn (nínú oyún).

Ìyẹn ni pé, láti ìrísí àtọ̀ sí ìrísí ẹ̀jẹ̀ dídì, lẹ́yìn náà sí bááṣí ẹran.

Yoruba - Nuh 71:14 · Tlawati