Yoruba

Al-Fajr · 89:21

كَلَّا إِذَا دُكَّتِ الْأَرْضُ دَكًّا دَكًّا

Translation

Rárá, (kò yẹ kó rí bẹ́ẹ̀). Nígbà tí wọ́n bá mi ilẹ̀ tìtì ní mímì tìtì (t’ó rún wómúwómú, tí kò sí kòtò, tí kò sí gelemọ),
Yoruba - Al-Fajr 89:21 · Tlawati