Yoruba

At-Takwir · 81:19

إِنَّهُ لَقَوْلُ رَسُولٍ كَرِيمٍ

Překlad

Dájúdájú (al-Ƙur’ān) ni ọ̀rọ̀ (tí A fi rán Jibrīl) Òjíṣẹ́, alápọ̀n-ọ́nlé,

Wo ìtọsẹ̀-ọ̀rọ̀ fún sūrah al-Hāƙƙọh; 69:40.

Yoruba - At-Takwir 81:19 · Tlawati